Baruch Spinoza

From Wikipedia, the free encyclopedia

Baruch Spinoza
Remove ads

Baruch Spinoza (Hébérù: ברוך שפינוזה Baruch Shpinoza, Pọrtugí: Bento de Espinosa, Látìnì: Benedictus de Spinoza) to di Benedict Spinoza (November 24, 1632 – February 21, 1677) je omo Portogi ara Hollandi elesin Ju amoye.[1] Pelu opolo onisayensi to ni, bi ise Spinoza se lagbara to ati se pataki to ko han titi ki o to ku. Loni, o je gbigba bi ikan ninu awon aselaakaye olokiki[2] imoye orundun 17k, to se ipilese fun Olaju orundun 18k[2] ati iseagbewo bibeli odeoni.[2] Nitori iwe re Ethics, to jade leyin iku re, ninu ibi to ti lodi si iseonimeji okan-ara Descartes, Spinoza je gbigba bi ikan ninu awon amoye pataki ninu Imooye apaiwoorun. Amoye ati akoitan Georg Wilhelm Friedrich Hegel so nipa gbogbo awon amoye igbalode pe, "E le je Asespinosa tabi ki e mo je amoye rara."[3]

Quick facts Orúkọ, Ìbí ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads