Friedrich Nietzsche

From Wikipedia, the free encyclopedia

Friedrich Nietzsche
Remove ads

Friedrich Wilhelm Nietzsche (October 15, 1844  August 25, 1900) (Pípè nì Jẹ́mánì: [ˈfʁiːdʁɪç ˈvɪlhɛlm ˈniːtsʃə]; in English UK: /ˈniːtʃə/, US: /ˈniːtʃi/[1]) je ara Europe ni orundun 19 to je onimo oye ati onimo filologi ijoun. O ko iwe agbeyewo lori esin, iwuwa, asa igbana, imoye ati sayensi, nipa lilo ede Jemani otooto.

Quick facts Orúkọ, Ìbí ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads