Bracket

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Bracket jẹ́ olórin orílè-èdè Nàìjíríà méjì kan, tí wọ́n ń kọ orin afropop àti R&B. Oŕkọ àwọn olórin méjèèjì yìí jẹ́ Obumneme Ali "Smash" àti Nwachukwu Ozioko"Vast".[1][2]

Quick facts Orúkọ àbísọ, Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi ...
Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads