Phyno
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Chibuzo Nelson Azubuike (tí wọ́n bí ní 9 October 1986), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ jẹ́ Phyno, jẹ́ olórin, olórin tàkásúfèé àti agbórinjáde ti orílè-èdè Nàìjíríà.[3][4] Phyno ti kọrin pẹ̀lú àwọn olórin bí i Olamide, Wizkid, Davido, Timaya, Flavour, Ruggedman, Bracket, J. Martins àti Mr Raw.[5]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads