Charles de Gaulle
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Charles André Joseph Marie de Gaulle (ìpè Faransé: [ʃaʁl də ɡol]Àdàkọ:IPA audio link, English: /ˈtʃɑrlz/ or /ˈʃɑrl dəˈɡɔːl/; 22 November 1890 – 9 November 1970) je was a French ogagun agba omo ile Fransi ati agba ilu to solori Free French Forces nigba Ogun Agbaye Keji. Leyin eyi o da Igba Oselu Karun Fransi ni 1958 o si di Aare akoko re lati 1959 de 1969.[1]
Gege bi omo ogun nigba Ogun Agbaye Akoko, ninu awon odun 1920 si awon odun 1930 de Gaulle gbajumo bi olugbowo awon oko ijagun ati baalu ijagun, to gba pe won le dopin ogun jija ninu ere. Nigba Ogun Agbaye Keji o di ipo Ọ̀gágun Ẹlẹ́ẹ̀ṣọ́ fun igbadie, nibi o ti lo oko ijagun ninu ija 1940 Isubu ile Fransi ni 1940, o si je ipo ninu ijoba Fransi ko to di pe Fransi subu.
O salo si Ilegeesi o si soro lori eto radio ti BBC se ni 18 Osu kefa, 1940, nibi tto ti unso fun awon ara Fransi pe ki won koju ija si Jemani Nazi[2] and organised the Free French Forces with exiled French officers in Britain.[3]
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads