Jẹ́mánì Nazi

From Wikipedia, the free encyclopedia

Jẹ́mánì Nazi
Remove ads

Jẹ́mánì Nazi ati Raik Keta ni awon oruko to wopo fun orile-ede Jemani labe ijoba Adolf Hitler ati Egbe Osise Sosialisti Apapo Jemani (NSDAP), lati 1933 de 1945. Raik Keta (Third Reich) () tokasi ijoba Nazi gege bi atele si Ile Obaluaye Romu Mimo igba ailaju ni Europe (962–1806) ati si Ile Obaluaye Jemani odeoni (1871–1918). Jemani Nazi ni oruko onibise meji, the Deutsches Reich (Raik Jemani), lati 1933 de 1943, nigba to di Großdeutsches Reich (Raik Jemani Titobiju).

Quick facts


Remove ads

Itoksi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads