Cissy Houston

From Wikipedia, the free encyclopedia

Cissy Houston
Remove ads

Emily "Cissy" Houston (oruko idile Drinkard; ojoibi September 30, 1933 o si ku ni Oṣu Kẹwa Ọjọ 7, Ọdun 2024)[3] je akorin soul ati gospel ara Amerika. Houston gba Ebun Grammy ni emeji fun awon orin re. Houston ni mama akorin Whitney Houston, iya-iya fun Bobbi Kristina Brown, aunti fun awon akorin Dionne ati Dee Dee Warwick, ati ibatan akorin opera Leontyne Price.

Quick facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads