Destiny Etiko
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Destiny Etiko tí wọ́n bí lọ́jọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1989 jẹ́ gbajúmọ̀ Òṣẹ̀rẹ́bìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó ti gba àmìn ẹ̀yẹ Òṣẹ̀rẹ́bìnrin tí ó ń dàgbà jù lọ ní àgbàlá sinimá àgbéléwò lédè Òyìnbó ti City People Movie Award for most Promising Actress (English) ní City People Entertainment Awards lọ́dún 2016.[1]
Remove ads
ìgbésí-ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀
Wọ́n bí Etiko sí abúlé kékeré kan tí ó ń jẹ́ Udi, ní Ìpínlẹ̀ Enugu lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ẹ̀yà ìgbò ni wọ́n. Etiko kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti garama rẹ̀ ní Ìpínlẹ̀ náà tí ó sìn gbàwé ẹ̀rí, First School Leaving Certificate àti West African Senior School Certificate. Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí dìgírì nínú ìmọ̀ iṣẹ́ tíátà ní yunifásítì ti Nnamdi Azikiwe University, ní ìlú Awka.[2]
Iṣẹ́ rẹ̀
Etiko bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò lọ́dún 2011. Ó di gbajúmọ̀ òṣẹ̀rẹ́ nígbà tí ó kópa nínú sinimá àgbéléwò kan tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Idemili tí gbajúgbajà olóòtú sinimá àgbéléwò, Ernest Obi ṣe lọ́dún, ṣùgbọ́n tí kò tètè jáde títí di ọdún 2014. but was not released until 2014. Ipa tí ó kó nínú sinimá àgbéléwò náà mú un wà nínú àwọn adíje àmì ti City People Entertainment Awards. Kí ó tó kópa nínú sinimá àgbéléwò Idemili, Etiko ti kópa ráńpẹ́ nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn sinimá àgbéléwò [2]
Remove ads
Àmìn ẹ̀yẹ
Aṣojú
Ilé iṣẹ́ aṣẹ̀ṣọ́ irun, Kesie Virgin Hair gbà á gẹ́gẹ́ bí aṣojú wọn lọ́dún 2019. [4][5]
Àtòjọ àwọn àṣàyàn sinimá àgbéléwò tí ó ti kópa
- The prince & I (2019)[6]
- Heart of Love (2019)
- My sisters love (2019)
- Poor Billionaire (2019)
- Virgin goddess (2019)
- Queen of love (2019)
- The Sacred Cowry (2019)
- The Return of Ezendiala (2019)
- Barren Kingdom (2019)
- Pains of the Orphan (2019)
- Clap of Royalty (2019)
- The Hidden Sin (2019)
- Family Yoke (2019)
- King’s Word (2019)
- Sound of Evil (2019)
- My Private Part (2019) as Stella
- Power of Royalty (2019)
- Sunset of Love (2019)
- London Prince (2019)
- Woman of Power (2019)
- Tears of Regret (2018)
- Evil Seekers (2017)
- Fear of a Woman (2016)
- 3 Days to Wed (2016)[6]
- The Storm (2016)
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads