Eucharia Anunobi

Òṣéré orí ìtàgé From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Eucharia Anunobi, (tí a bí ní 25 Oṣù Karùn-ún 1965) jẹ́ òṣèré ọmọ Nàìjíríà, Olùgbéréjáde, àti Pásítọ̀. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínu fiimu Abuja Connection[1] Ó rí yíyàn níbi 2020 Africa Magic Viewers’ Choice Awards fún ẹ̀bun òṣèré tó peregedé jùlọ ní ipa àtìlẹyìn nínu fiimu tàbí eré tẹlifíṣọ́nù.[2]

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Ọmọ orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti iṣẹ́ ìṣe rẹ̀

A bí Eucharia ní Owerri, Ìpínlẹ̀ Imo, ó sì parí ilé-ìwé alákọ́bẹ̀rẹ̀ àti ilé-ẹ̀kọ́ girama níbẹ̀ ṣááju kí ó tó tẹ̀ síwájú lọ sí Institute of Technology, Enugu níbití ó ti gba oyè National Diploma nínu ìmọ̀ Mass Communication.[3] Ó tún ní oyè Bachelor of Arts lẹ́hìn tí ó kẹ́ẹ̀kọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásitì Nàìjíríà, ti ìlu Nsukka.[4] Eucharia di gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínu fiimu Glamor Girls ní ọdún 1994, ó sì ti ní ìfihàn nínu àwọn fiimu tó lé ní 90 tí ó fi mọ́ Abuja Connection àti Letters to a Stranger.[5] Ó n ṣiṣẹ́ ajíhìnrere lọ́wọ́lọ́wọ́ ní ilé ìjọsìn kan ní ìlu Ẹgbẹ́dá, Ìpínlẹ̀ Èkó.[6] Eucharia pàdánù ọmọkùnrin rẹ̀ kan, Raymond, ẹnití ó ṣe àpèjúwe rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ jùlọ [7] sí àìsàn àrùn inú ẹ̀jẹ̀ ní Oṣù Kẹẹ̀jọ Ọjọ́ 22, Ọdún 2017. Ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́ẹ̀dógún.[8]

Remove ads

Àkójọ àwon eré rẹ̀

  • Small Chops (2020)
  • The Foreigner's God (2018)
  • Breaking Heart (2009)
  • Heavy Storm (2009)
  • Desire (2008)
  • Final Tussle (2008)
  • My Darling Princess (2008)
  • Black Night in South America (2007)
  • Area Mama (2007)
  • Big Hit (2007)
  • Bird Flu (2007)
  • Confidential Romance (2007)
  • Cover Up (2007)
  • Desperate Sister (2007)
  • Drug Baron (2007)
  • Fine Things (2007)
  • Letters to a Stranger (2007)
  • Sacred Heart (2007)
  • Short of Time (2007)
  • Sister’s Heart (2007)
  • Spiritual Challenge (2007)
  • The Trinity (2007)
  • Titanic Tussle (2007)
  • When You are Mine (2007)
  • Women at Large (2007)
  • 19 Macaulay Street (2006)
  • Emotional Blunder (2006)
  • Evil Desire (2006)
  • Heritage of Sorrow (2006)
  • Joy of a Mother (2006)
  • My Only Girl (2006)
  • Occultic Wedding (2006)
  • Thanksgiving (2006)
  • The Dreamer (2006)
  • Unbreakable Affair (2006)
  • 100% Husband (2005)
  • Dangerous Blind Man (2005)
  • Dorathy My Love (2005)
  • Extra Time (2005)
  • Family Battle (2005)
  • Heavy Storm (2005)
  • Home Apart (2005)
  • No Way Out (2005)
  • Rings of Fire (2005)
  • Second Adam (2005)
  • Secret Affairs (2005)
  • Shadows of Tears (2005)
  • Sins of My Mother (2005)
  • The Bank Manager (2005)
  • To Love a Stranger (2005)
  • Torn Apart (2005)
  • Total Disgrace (2005)
  • Tricks of Women (2005)
  • Unexpected Mission (2005)
  • War for War (2005)
  • Abuja Connection (2004)
  • Deadly Kiss (2004)
  • Deep Loss (2004)
  • Diamond Lady 2: The Business Woman (2004)
  • Expensive Game (2004)
  • Falling Apart (2004)
  • For Real (2004)
  • Home Sickness (2004)
  • Last Decision (2004)
  • Love & Marriage (2004)
  • Miss Nigeria (2004)
  • My Own Share (2004)
  • Never Say Ever (2004)
  • Not By Power (2004)
  • Official Romance (2004)
  • Price of Hatred (2004)
  • The Maid (2004)
  • Abuja Connection (2004)
  • Armageddon King (2003)
  • Computer Girls (2003)
  • Emotional Pain (2003)
  • Expensive Error (2003)
  • Handsome (2003)
  • Hot Lover (2003)
  • Lagos Babes (2003)
  • Mother’s Help (2003)
  • Reckless Babes (2003)
  • Show Bobo: The American Boys (2003)
  • Sister Mary (2003)
  • Society Lady (2003)
  • The Only Hope (2003)
  • The Storm is Over (2003)
  • What Women Want (2003)
  • Evil-Doers (2002)
  • Not with my Daughter (2002)
  • Orange Girl (2002)
  • Death Warrant (2001)
  • Desperadoes (2001)
  • The Last Burial (2000)
  • Benita (1999)
  • Heartless (1999)
  • Died Wretched (1998)
  • Battle of Musanga (1996)
  • Back Stabber (1995)
  • Glamour Girls (1994)
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads