Owerri

From Wikipedia, the free encyclopedia

Owerri
Remove ads

Owerri ( /ˈwɛri/ oh-WERR-ee,[1] Igbo: Owèrrè)[2] ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ ImoNàìjíríà, ìlú náà wà láàrin ilẹ̀ igbó.[3] Òun tún ni ìlú tí ó tóbi jù ní Ìpínlẹ̀ Imo, ìlú Orlu, Okigwe àti Ohaji/Egbema sì ni ó tẹ̀lẹ́. Owerri ní ìjọba ìbílè mẹta, àwọn ni Owerri Municipal, Owerri North àti Owerri West, ìlú Owerri ní àwọn olùgbé 1,401,873 ní ọdun 2016. Owerri pín àlà pẹ̀lú Otamiri River ní apá ìwọ̀ oòrùn rẹ̀ àti Nworie River ní apá gúúsù rẹ̀.[4]

Quick facts Coordinates: 5.485°N 7.035°E /, State ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads