Fireboy DML
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Adedamola Oyinlola Adefolahan (tí wọ́n bí ní 5 February 1996),[2] tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Fireboy DML, jẹ́ olórin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ-ẹgbẹ́ YBNL Nation, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tí Olamide dá sílẹ̀.[3]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads