Funmi Aragbaye

Akọrin obìnrin From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Funmi Aragbaye (tí a bí ní ọjọ́ 5 oṣù 1954) jẹ́ olórin ìhìnrere ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,akọrin àti oníwàásù afẹ́fẹ́.[1][2] Ó fẹ́ Bola Aragbaye tí o ti di olóògbé,pẹ̀lú ọmọ mẹta.[3]

Quick facts Ọjọ́ìbí, Orílẹ̀-èdè ...
Remove ads

Àtòjọ àwọn orin rẹ̀

  • Olorun Igbala (1983)
  • Sioni ilu ayo' (1983)
  • pin Rere (Good Portion)'
  • Glory of God (Ogo Oluwa)

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads