Gani Adams

Abíodún From Wikipedia, the free encyclopedia

Gani Adams
Remove ads

Fáìlì:Ààrẹ Ọ̀nà Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iléẹ̀kọ́ gíga ...

Iba Gàníyù Adams t́i fi ìgbà kan jẹ́ olórí ẹgbẹ́ ọmọ Odùduwà tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí O.P.C, A bí Ọ̀túnba Ganiyu Adam ní (ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù kẹrin ọdún 1970). Ó jẹ́ ajìjàngbara àti Ààrẹ Ọ̀nàkakaǹfò. [1]

Remove ads

Ìgbẹ́ ayé rẹ̀

Wọ́n bí Gani Adams ni ọjọ́ kẹẹ̀dọgun oṣù kẹrin ọdún 1970, ní Arigidi-Akoko tí wọ́n pè ní Àkókò North-west local government,Ondo State ni òdé òní.

Ẹ̀kọ́

Gani Adams bẹ̀rẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ rẹ̀ ni Army Children's School, Otukpo, Ìpínlè Benue. Sùgbọ́n nítorí irú ìṣẹ́ bàbá rẹ, wọ́n kó lọ sí ìlú Eko níbi tí o ti parí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹrẹ̀ ní Municipal Primary School ní SurulereÌpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1980. Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ alákọ̀bẹrẹ̀ rẹ̀, o tẹsìwàjú lọ sí Ansar-Ud-deen Secondary School, Randle Avenue, Surulere. Lẹ́yìn ẹ̀kọ́ girama ,ó lọ kọ́ nípa ṣíṣe àwọ́n ọ̀ṣọ́ ilé tí ó sì parí ní ọdún 1987.[2]

Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads