Goodluck Jonathan

Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia

Goodluck Jonathan
Remove ads

Goodluck Jonathan [ọjọ́ìbí 20 Noveber (Belu)1957][1] jẹ́ olósèlú ọmọ ilè Nàíjíríà àti Àare orílé èdè Nàíjíríà láti May (Èbìbi) 6, 2010. Ohun ní igbákejì Àare ilè Nàíjíríà sí àare Umaru Músá YarAdua kí ó tó dibo fun gégé bí adìbó àare ni 9 February, 2010 nítorí aìsàn tó dé ba YarAdua mólè. Léyin ti Yar'Adua kú ní May (Èbìbi) 5, 2010, jónáthàn di [2] bakan yéyé ó tun jẹ gómìnà ìpínlè Bàyélsà larin 9 ọpẹ́(December) 2005 àti 28 Ebìbí (May) 2007 àti igbákejì Gòmìnà Ipinle [3]

Quick facts President of Nigeria, Vice President ...
Remove ads

Igbesi aye Ibẹrẹ

G

Goodluck Jonathan ní a bi ni 20 Oṣu kọkanla ọdun 1957 ni Ilu Ogbia si idile Kristiani kan ti awọn ti n ṣe ọkọ-ọkọ, làti ẹya Ijaw to kere ni Ipinlẹ Bayelsa.


Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads