Ilfenesh Hadera

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Ilfenesh Hadera
Remove ads

Ilfenesh Hadera (ti a bi ni ojo kini osu kankanla odun 1985) je osere Ethiopian-American . O ko pa ninu fiimu Baywatch ti oj jade ni odun 2017 gege bi Stephanie Holden . Ni ojo kankandilogbon osu kesan, Hadera bera si ni kopa Mayme Johnson, iyawo Bumpy Johnsonni ifi lole jara titi American , Godfather of Harlem lori Epix.[1]

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Remove ads

Igbesi aye ibẹrẹ

A bi Hadera ni ojo kini osu kankanla ni ilu Harlem.[2] Oje omo ilu Ethiopia ati Europea lapapo.[3] Baba e Asfaha je asasala Ethiopia Tigrayan ati oludasili African Services Committee, NGO ti o wa ni ilu Harlem eyi ti o man shey iranlowo fun awon oni irin ajo to wa lati Africa[4]. Iya re Kim Nichols je oludari ASC, ohun ati Hadera man yonda arowan le pelu orisirisi eniyan ki oto bere ise osere .[5][6] Hadera se ise olounje fun odun mewa ki oto bere ere sise.[7]

O lọ si The Harlem School of the Arts, atẹle nipasẹ Fiorello H. LaGuardia High School. Hadera lọ siwaju lati gba MFA ni Awọn ẹkọ ọrọ ati Iṣe lati RADA/King's College London.[8]

Remove ads

Iṣẹ

Ni odun 2010 Hadera jade ninu fiimu 1/20. Fun igba akoko[9]

Ohun ati Spike Lee ma jon sise ni opolopo igba, oti kopa ninu Da Brick, The Blacklist, Oldboy, Show Me a Hero, Chi-Raq, Chicago Fire, The Punisher ati She's Gotta Have It.

Hadera ṣe alabaṣiṣẹpọ gege bi Stephanie Holden ninu fiimu odun 2017 Baywatch, ati ni ọdun 2018 o ṣe irawọ bi Kay Daniels ninu jara TV Billions. O ni o ni a ti nwaye ipa ninu awọn Showtime Series Billions , gebi akọwé fun billionaire Bobby Axelrod, dun nipa Damian Lewis .

Remove ads

Filmography

Fiimu

More information Year, Title ...

Tẹlifisiọnu

More information Year, Title ...

Awọn itọkasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads