Ọba

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ọba
Remove ads

Ọba jẹ́ ọkùnrin tí ó ń ṣolórí Ìlú ilẹ̀ tàbí orílẹ̀-èdè nítorí wípé ó lẹ́tọ̀ọ́ láti wà nípa adarí. O le je taara lati inu ebi re tabi nitoripe ebi re lokan. Opo awon ni ile Yoruba lori bayi.[1][2] Won ni awon afọbajẹ ti won gbimo ibo ni tabi inu ebi wo ni oba to kan yio ti wa.[3] Ni Europe oba n je lati inu ebi kanna. Yio gori ite taara lati odo bàbá tabi ìyá re.

Thumb
Ọba Ataọ̀jà ilẹ̀ Yorùbá

Iyawo oba ni a n pe ni ayaba[4] tabi ayaoba. Ni Europe obìnrin yi le gun ori ite ti oba ba ku, eyi ko je be ni ile Yoruba nibi ti obinrin ko le di oba.

Ti olori orile-ede kan ba je oba a n pe iru ijoba yi ni idobaje, ti oba na si n je adobaje.


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads