Jacob Zuma

From Wikipedia, the free encyclopedia

Jacob Zuma
Remove ads

Jacob Zuma jẹ́ ààrẹ orílẹ̀ èdè Gúúsù Áfíríkà tẹ́lẹ́.[2][3][4] Ó wolé ní osù kejìlá odún 2006 gégé bí alága fún egbé African National Congress (ANC) ní Guusu Afrika.[5] Olóyè ni ó jé ní àárín àwọn Zulu. Ní ọjọ́ karùn-ún osù kìíní odún 2007, ó fé Nompumeledo Ntuli, ọmọ ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó rẹ̀ karin lẹ́yìn ìgbà tí ó ti bí ọmọ méjì fún un. 1943 ni wọ́n bí Jacob Zuma. Ìyàwó rẹ̀ kan tí orúkọ rẹ̀ ní jẹ́ Kate pa ara rẹ̀ ní ọdúin 2000 nítorí pé ó ní ìgbéyàwó tí àwọn ti ṣe fún ọfún mẹ́rìnlélógún kò rọgbọ. Ọmọ ọdún mẹ́rìnlélógójì ni Kate nígbà náà: Ní ọdún 2005 ni President thabo Mbaki yọ Zuma kúrò ní ipò igbákejì àrẹ nítorí ìwà ìbàjẹ́.[6] Ní ọdún 2006 ni wón fi ẹ̀sùn kan Zuma pé ó fi ipá bá obìnrin kan tí ó ní HIV lo pò. Kò jẹ̀bi ẹ̀sùn náà. Ni Oṣu Kẹsan ọdun 2021, idajọ ododo jẹrisi idalẹjọ ti Jacob Zuma si oṣu mẹẹdogun ninu tubu.[7]

Quick facts His Excellency, President of South Africa ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads