Kgalema Motlanthe

From Wikipedia, the free encyclopedia

Kgalema Motlanthe
Remove ads

Kgalema Petrus Motlanthe (pìpè [ˈkx͡ɑ.lɪ.mɑ mʊ.ˈtɬ͡’ɑ.n.tʰɛ])[1] (bibi 19 July 1949) je oloselu ara ile Guusu Afrika to di Aare ile Guusu Afrika larin 25 September 2008 ati 9 May 2009, lati se imupari akoko keji Thabo Mbeki ti o siwo ise gege bi Aare.[2]

Quick facts His Excellency, 3rd President of South Africa ...

Motlanthe tún jẹ́ Igbakeji Aare si Jacob Zuma to je Aare ile Guusu Afrika láti 2009 títí di 2014.

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads