Klára Zakopalová
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Klára Zakopalová (Orúkọ tí sọọ́ ni ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ni Klára Koukalová) tí a sì bí ní ọjọ́ kẹrinlélógún oṣù kejì ọdún 1982 ní ìlú Prague, Czechoslovakia) ó jẹ́ àgbà ọ̀jẹ̀ obìnrin agbá bọ́ọ̀lù tẹnísìì ti orílẹ̀ èdè Czech. A bi ní Prague ó sìí gbé ní bẹ̀.
Remove ads
Ìgbésí ayé rẹ̀
Ní ọjọ́ kẹfà oṣù kẹfà ọdún 2006, Klára fẹ́ Agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀ èdè Czech kan, Jan Zakopal,[1] ṣùgbọ́n ìgbéyàwó wọn túká ní oṣù kínní ọdún 2014.[2] Láàrin oṣù kẹfà ọdún 2006 sí oṣù kẹta ọdún 2014, ó lọ orúkọ ọkọ rẹ̀, Zakopalová nínú àwọn ìdíje tí ó ti kópa, ṣùgbọ́n ó yí orúkọ rẹ̀ padà sí Koukalová ní oṣù kẹrin ọdún 2014.
Àwọn eré rẹ̀ lórí pápá
Àdágbá
Doubles
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads