Last Flight to Abuja
eré amóhùn máwòrán tí ójáde ní ọdún 2012 From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Last Flight to Abuja jẹ́ fíìmù 2012 Nàìjíríà àjálù tí a kọ nípasẹ̀ Tunde Babalola, tí Obi Emelonye ṣe àti mú jáde, tí Omotola Jalade Ekeinde, Hakeem Kae-Kazim àti Jim Iyke ṣe. Tí a yàwòrán ní Ìlú Èkó, fíìmù náà gba àwọn yíyan àbùn márùn-ún ní ọdún 2013 Africa Movie Academy Awards, tí ó borí ní ẹ̀ka “Fíìmù tí ó dára jùlọ nípasẹ̀ orísun Áfíríkà kan ní ilẹ̀ òkèèrè”. [2][3][4] Ní ọjọ́ márùn-dín-lógún, oṣù kẹfà ọdún 2020, 'Last Flight to Abuja' bẹ̀rẹ̀ àfihàn lórí Netflix ní ọdún mẹ́jọ lẹ́hìn tí ó kọ́kọ́ ṣe àfihàn ní Ìlú Lọ́ndọ́nù. [5]
Remove ads
Àwọn Òṣèré
- Omotola Jalade Ekeinde - Suzie
- Hakeem Kae-Kazim - Adesola
- Ali Nuhu - Dan
- Jim Iyke - David
- Anthony Monjaro - Aircraft captain
- Uru Eke - Air hostess
- Tila Ben - Passenger
- Jide Kosoko - Chief Nike
- Celine Loader - Captain Seye
- Uche Odoputa - Efe
- Jennifer Oguzie - Yolanda
- Samuel Ajibola
- Ashaju Oluwakemi
- Nneka J. Adams
Ṣíṣe Rẹ̀
Ní àsìkò tí ó ń ṣiṣẹ́ fíìmù yìí, Emelonye ní láti bá àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀, àwọn ilẹ́-ìfowópamọ́, àti àwọn òṣìṣẹ́ aláṣẹ wọ̀ ní pápá-ọkọ̀ òfurufú Murtala Muhammed tó wà nílùú Èkó.[6]
Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads