Laycon

From Wikipedia, the free encyclopedia

Laycon
Remove ads

Ọlámilékan Moshood Agbélẹ̀ṣe tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Laycon ní woọ́n bí lọ́jọ́ kẹjọ oṣù kọkànlá ọdún 1993,(8 November, 1993) jẹ́ gbajúmọ̀ olùdíje tí ó borí ìdíje ètò-ìgbafẹ́ ẹ̀rọ tẹlifíṣàn, Big Brother Naija (ìpele karùn-ún), ó jẹ́ olórin-tàkasúfèé àti oǹkọ̀wé orin ọmọ orilẹ̀-èdè Nàìjíríà

Quick facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Remove ads

Ìgbésí-ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀

Wọ́n bí Ọlámilékan Moshood Agbélẹ̀ṣe tí gbogbo ènìyàn mọ́ sí Laycon sí ìlú Èkó, ní Nàìjíríà.[1][2] ṣùgbọ́n, ó jẹ́ ọmọ bibi ìlú Bájùwẹ̀n, ní ỌdẹdáÌpínlẹ̀ Ògùn.[3][4]

Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ philosophy ní University of Lagos lọ́dún 2012 sí 2016.[5][6][7]

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads