Liberia

From Wikipedia, the free encyclopedia

Liberia
Remove ads

Làìbéríà tabi Orile-ede Olominira ile Làìbéríà je orile-ede ni Iwoorun Afrika. O fi ègbé kan Ilè Sàró tí a mò si Sierra Leone ní ìwǫ oòrùn, orílę èdè Guinea ni gúúsù ati orílę èdè Côte d'Ivoire ní ìlà oòrùn. Etí Òkun Làìbéríà kún fún ijù igi mangrove nìbitì ilę nínú loun pęlú èrò kékeré ję kìkì ijù tí ó na apá sí ìtélè ewéko gbígbe. Ilu naa ni o ni 40% ninu eyi ti o seku ni igi Iju Guinea ti Apa Guusu. Afefe ilu Làìbéríà je ti gbigbona ila idameji aye, pelu òjo pupo ni osu May titi di osu October ni asiko òjò ati afefe oye lile fun iyoku odun.

Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ LàìbéríàRepublic of Liberia, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...
Remove ads

Àwọn Ìtọ́ka sí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads