Mike Bamiloye

Oníṣẹ́-èdè fílìmù Gọ́sìpẹlì àti Akẹ́kọ̀ọ́ fílìmù From Wikipedia, the free encyclopedia

Mike Bamiloye
Remove ads

Mike Ayọ̀bámi Bámilóyè ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹ́rin ọdún 1960. Jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé, adarí eré, olùgbéré-jáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [3] Ó jẹ́ ajíyìn-rere tí ó ma ń lo eré oníṣẹ́ láti fi jèrè ọkàn àwọn ènìyàn, ó sì tún jẹ́ Olùdásílẹ̀ àti Ààrẹ Mount Zion Faith Ministries[4] àti ti Mount Zion Television. Ó sì tú jẹ́ ọ̀kan lára ìjọ Christ Apostolic Church.

[1][2]

Quick facts Michael Àbáyọ̀mí Bámilóyè (MAB), Ọjọ́ìbí ...
Remove ads

Ìbẹ̀rẹ̀ Ayé rẹ̀

Wọ́n bí Mike ní ìlú Ìjẹ̀bú-Jẹ̀ṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹ́rin ọdún 1960.[5] Ìyá rẹ̀ kú ní nígbà tí ó wà nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́rin. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ obìnrin tí ó jẹ́ páítọ̀ Mrs. Felicia Adépọ̀jù Adésànyà ni ó tọ́jú rẹ̀ títí ó fi dàgbà kí ó tó lè mójú tó ara rẹ̀. o lọ si ile-ẹkọ giga ikẹkọ awọn olukọ Divisional College ní ìlú Ìpetu-modù. Ó dá ìjọ Mount Zion ní ọjọ́ Karùún oṣù Kẹrin ọdún 1985. [6] Eré tí ó gbé jáde ni Hell in Conference ni wọ́n ṣàfihàn rẹ̀ ní National Christian Teachers Conference ní ọdún 1986 ní ìlú IléṣàÌpínlẹ̀ Ọ̀ṣun .[7] Ó ti kópa, darí ati gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọkan jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún sẹ́yìn. [8]

Remove ads

Ìgbésí ayé rẹ̀

Ní inú oṣù kẹ́jọ ọdún 1985, ìyàwó rẹ̀ arábìnrin Gloria Bámilóyè gbà láti jẹ́ aya rẹ̀, èyí ni ó sì bẹ̀rẹ̀ ìpìlẹ̀ ìjọ wọn (Mount Zion). Wọ́n bí àwọn ọmọ mẹ́rin (Damilola, Joshua, and Darasimi Mike-Bamiloye).[9]

Àwọn Ìtọ́kasí

More information Year, Film ...

Ẹ tún lè wo

  • List of Yoruba people

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads