Order of the Niger

From Wikipedia, the free encyclopedia

Order of the Niger
Remove ads

Àdàkọ:Infobox order

Thumb
The order takes its name from the River Niger
Thumb

Nàìjíríà gba olómìnira ní ayájọ́ ọjọ́ kìíní oṣù kẹwàá 1960, ó sì di orílẹ̀-èdè olómìnira ní ọdún 1963. Orílẹ̀-èdè yí ṣe agbékalẹ̀ amì-ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá méjì kan kalẹ̀ láti ma fi bu ọlá fún àwọn lààmì-laaka ènìyàn láwùjọ. Àwọn àmì-ẹ̀yẹ náà ni: Order of the Niger àti Order of the Federal Republic.[1]

Àmì-ẹ̀yẹ GCON

Àwọn amì-ẹ̀yẹ méjì tí wọ́n lákaakì jùlọ nínú àwọn amì-ẹ̀yẹ náà ni: Grand Commander in the Order of the Federal Republic . Ìsọ̀rí àkọ́kọ́ yí jẹ́ amì-ẹ̀yẹ tí ó tọ́ sí ẹnikẹ́ni tí ó bá ti jẹ Ààrẹ àti igbákejì Ààrẹ, Olórí ilé ìgbìmọ̀ Aṣòfin, Adájọ́ Àgbà fún orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.


Ìsọ̀rí amì-ẹ̀yẹ náà

Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kọ́ṣe ìjọba ìjọba àmúnisìn ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì nípa fífi amì-ẹ̀yẹ da àwọn lààmì-laaka àti ọ̀tọ̀kùlú ìlú lọ́lá. Amì-ẹ̀yẹ yí ni ó wà fún àwọn ológun àti àwọn tí kìí ṣe ológun. Wọ́n sì ma ń kọ̀wé ránṣẹ́ sí àwọn tí wọ́n bá yàn láti fi amì-ẹ̀yẹ náà dá lọ́lá.

  • Grand Commander of the Order of the Niger (GCON)
  • Commander of the Order of the Niger (CON)
  • Officer of the Order of the Niger (OON)
  • Member of the Order of the Niger (MON)
Remove ads

Àwọn tí wọ́n ti amì-ẹ̀yẹ náà rí

[2]

More information S/NO, Orúkọ ...
Remove ads

Àwọn itọ́kasí

Àwọn Ìtàkùn ìjásóde

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads