Pakístàn

orílẹ̀-èdè ní Ásíà From Wikipedia, the free encyclopedia

Pakístàn
Remove ads

Pakístàn (/ˈpækɪˌstæn/  ( listen) tabi /ˌpɑkɨˈstɑːn/  ( listen); Urdu: پاکِستان) (Pípè ní Urdu: [paːkɪsˈtaːn]  ( ẹ tẹ́tí gbọ́)), lonibise bi Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn (Urdu: اسلامی جمہوریہ پاکِستان) je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni ile etiomi to to 1,046-kilometre (650 mi) leba Omiokun Arabia ati Omiala Oman ni guusu, be sini o ni bode mo Afghanistan ati Iran ni iwoorun, India ni ilaorun ati Shaina ni ookan ni ariwailaorun.[7] Bakanna Tajikistan na sunmo Pakistan sugbon aaye Odede Wakhan tinrin pin won soto. Letanletan o budo si ipo larin awon agbegbe pataki Guusu Asia, Alaarin Asia ati Ibiarin Ilaorun.[8]

Quick Facts Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ PakístànIslamic Republic of Pakistan اسلامی جمہوریہ پاکستان Islāmī Jumhūrī-ye Pākistān, Olùìlú ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads