Èdè Sindhi

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Ede Sindhi (Sindhi: سنڌي, Urdu: سندھی,Devanagari script: सिन्धी, Sindhī) je ede ni agbegbe Sindh ni Pakistan loni. Iye awon eniyan to un so ni Pakistan je 24,410,910, bakanna ni India iye awon to n so je 2,535,485.[1] O je ede iketa ni Pakistan, ati ede ibise ni Sindh ni Pakistan. O tun je ede ibise ni India. Kadi idanimo ti ijoba ile Pakistan un te jade je ni ede meji nikan pere, Sindhi ati Urdu.

Quick facts Sindhi, Sísọ ní ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads