Paul Dirac
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Paul Adrien Maurice Dirac, OM, FRS (pípè /dɪˈræk/ di-RAK; 8 August 1902 – 20 October 1984) je onimofisiiki oniro ara Britani. Dirac se afikun pataki si ibere isise ero ayosere ati agbaraonina ayosere. O di ipo Ojogbon Aga Lukas fun Mathematiiki mu ni Yunifasiti ilu Cambridge, o si lo odun merinla togbeyin laye re ni Florida State University.
Ninu awon awari re, o sagbekale isodogba Dirac, eyi salaye iwuwa awon fermion eyi lo si faye gba isotele wiwa olodi elo.
Dirac pin Ebun Nobel ninu Fisiksi fun 1933 pelu Erwin Schrödinger, "fun sisawari awon iru iro atomu tuntun to wulo."[2]
Remove ads
Igba ewe
Paul Dirac je bibi ni ilu Bristol,[3] Ilegeesi, ni adugbo Bishopston lo gbe dagba.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
Iwe kika lekunrere
Ijapo Interneti
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads