Ray Charles

From Wikipedia, the free encyclopedia

Ray Charles
Remove ads

Ray Charles (September 23, 1930  June 10, 2004) je olorin omo orilee-ede Amerika. Charles je asiwaju ninu iru orin soul larin awon odun 1950 nipa sisadalu rhythm & blues, gospel, ati blues sinu awon awo orin re ni Atlantic Records.[1][2]

Quick facts Background information, Orúkọ àbísọ ...


Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads