Ìpínlẹ̀ Rivers
Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Ìpínlẹ̀ Rivers tí a tún mọ̀ bíi Rivers, ni ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà 36. Gẹ́gẹ́ bí dátà ìkanìyàn tó jáde ní ọdún 2006 ṣe fihàn, ìpínlẹ̀ náà ní iye ènìyàn 5,198,716, èyí sọ ọ́ di ìpínlẹ̀ tó ní iye èniyàn púpọ̀jùlọ kẹfà ní Nàìjíríà.[5] Olúìlú àti ìlú tótóbijùlọ rẹ̀ ni Port Harcourt. Ìlú Port Harcourt ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́bí gbọ̀ngàn àwọn ilé-iṣẹ́ epo. Ìpínlẹ̀ Rivers jámọ́ Òkun Atlantiki ní gúúsù, ó ní bodè mọ́ àwọn ìpínlẹ̀ Imo and Abia ní àríwá, ìpílẹ̀ Akwa Ibom ní ìlàòrùn, àti àwọn ìpínlẹ̀ Bayelsa àti Delta ní ìwọ̀òrùn. Ìpínlẹ̀ Rivers ní ọ̀pọ̀ ẹ̀yà tí nínú wọn ni: àwọn Ikwerre, àwọn Ijaw, àwọn Ògóni àti àwọn ẹ̀yà púpọ̀ míràn. Orúkọ fún àwọn ará ìpínlẹ̀ yìí ni "Riverians" tàbi "àwọn ará Rivers".[6]
Apá inú ìpínlẹ̀ náà jẹ́ ẹgàn tútù olóoru.
Remove ads
Ítàn Ìdásílẹ̀
Ìpínlẹ̀ Rivers gba orúkọ rè nípase awọn odò ti o la kojá.
Ijọba Ìbílẹ̀
Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Rivers jẹ́ mẹ́tàlẹ́lógún tí alága ìbílẹ̀ n se akoso gbogbo ìbílè na:
Remove ads
Awọn èdè
Awọn orísìrísí èdè tí ó wa ní ìpínlè Rivers nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Rivers:[7]
Èkó
Ilé ẹ̀kọ́ alakobere àti girama
Títí di ọdún 1999, ìpínlẹ̀ na ni ile-ẹkọ alakobere bí 2,805 áti ti girama bi 243 tó jẹ́ ti ijọba.
Ilé ẹ̀kọ́ gíga
- Captain Elechi Amadi Polytechnic[8]
- Eastern Polytechnic
- Federal College of Education (Technical), Omoku.
- Ignatius Ajuru University tí ó wà ní Rumuolumeni, Nkpolu Oroworukwo and Ndele.
- Kenule Beeson Saro-Wiwa Polytechnic
- PAMO University of Medical Sciences,Elelenwo, Port Harcourt
- Rivers State University.
- University of Port Harcourt,[9] Choba.
- Ken Saro Wiwa Polytechnic at Bori.
- School of Health Technology, Port Harcourt
- School of Nursing and Midwifery, Rumueme, Port Harcourt.[10]
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads