Sagamu

From Wikipedia, the free encyclopedia

Sagamumap
Remove ads

Sagamu tàbí Ishagamu jẹ́ ìlú àti olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ kan tí ó wà ní apá Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn Ìpìnlẹ̀ Ògùn lẹ́gbẹ̀ẹ́ Odò Ibu.[2] Sagamu sì jẹ́ àkójọpọ̀ ìlú mẹ́tàlá ní ìpínlẹ̀ Ògùn lọ́nà odò Ibu àti odò Ewuru, láàrin ipinle Eko àti Ibadan. Wọ́n sì dasílẹ̀ láàrin sẹ́ńtúrì kọkàndínlógún nípa sẹ̀ ọmọ-ẹgbẹ́ Yorùbá,[3]ní apá Guusu Ìwọ̀-oòrun orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àwọn ìlú mẹ́tàlá tí ó wà nínú rẹ̀ ni: Makun, Ofin Sonyindo, Epe, Ibido, Igbepa, Ado, Oko, Ipoji, Batoro, Ijoku, Latawa ati Ijagba.[4][5] Ó sì jẹ́ olú-ìlú Rẹ́mo, ẹni tí ó jẹ́ apàṣẹ ìlú Remo ni a mọ̀ sí Oba Akarigbo. Ìlú Ofin sì ni ààfin Ọba Akarigbo wà.

Quick Facts Sagamu Orisagamu, Country ...
Remove ads

Àwọn èèyàn tó lààmìlaaka láti ìlú Sagamu

Àwọn àtòjọ àwòrán ìlú Sagamu

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads