Adebayo Ogunlesi
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Adebayo "Bayo" O. Ogunlesi CON (tí a bí ni December 20, 1953) jẹ́ agbẹjọ́rò àti oní-ìdókòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria.[1][2] Òun ni olùdarí àgbà fún Global Infrastructure Partners (GIP). Ogunlesi fìgbà kan jẹ́ olórí wọn ni Credit Suisse First Boston[3] kí wọ́n tó yàn án sípò alága.[4]
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads