Sam Cooke
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Samuel Cook[1] (January 22, 1931 – December 11, 1964), to gbajumo bi Sam Cooke, je akorin gospel, R&B, soul, ati pop ara Amerika, akorin, ati onisowo. O je gbigba bi ikan ninu awon asiwaju ati oludasile orin soul.[2] Wo unpe bi Oba Orin Soul fun iru ohun ikorin re ati ipa to ni lori orin agbaye odeoni. Ipa re lori Orin Soul lo fa idide Aretha Franklin, Bobby Womack, Curtis Mayfield, Stevie Wonder, Marvin Gaye, o si je ki awon akorin bi Otis Redding ati James Brown o gbajumo.[3][4][5]
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads
