Sani Abacha
Olóṣèlú From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Sani Abacha (20 September 1943 – 8 June 1998) je Ogagun Ile-Ise Ologun ile Naijiria ati Olori orile-ede Naijiria lati ojo 17 osu Kokanla odun 1993 titi de ojo 8 osu Kefa 0dun 1998 to ku lojiji. [1][2]
Remove ads
ìgbé ayé rẹ
Wọn bí Abacha ní ìlú Kano ni Nàìjíríà.[3] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Nigeria Military Training College tí Ìlú Kaduna Ọgbà ipò igbimọ in Ọdún 1963 leyin tí ó dé láti ikẹ eko tó cadeti ni ìlú Aldershot ni England.
Ìgbà Ikú rẹ
Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹfà ni ọdún 1998,abacha ku si Aṣọ Rock tí àwọn Ààrẹ ni ìlú Abuja[2].Wọn sìn Abacha ní ìlà náà tí Mùsùlùmí. Àwọn kàn ní májẹ lè ní opáa, àwọn kan ni àwọn apá yàn ni wọ́n paa, àti bẹẹbẹẹ ló ní pàtó kosi ẹni tí ó mọ ìdí ikú rẹ.Lẹ́yìn ikú rẹ, wọn fi Ọgbẹ́ni Abdulsalami Abubakar ṣe olú dárí tí ìpínlẹ́ ni Oṣù Kẹ̀wá ọdún 1998[4].
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Àwon Ìtókasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads