Sarah Alade

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Sarah Alade jé omo orílé èdè Nàìjíríà ti o je adele gomina Central Bank of Nigeria, ni asiko ti Lamido Sanusi wa ni idaduro ki saa re o to pari.[1]. Olori orile-ede Nàìjíríà nigba naa, President Goodluck Jonathan ni o yan ni 20 February 2014.[2] A yan Alade gege bi adele gomina Central Bank of Nigeria lati 20 February 2014 titi ti a fi pada yan Godwin Emefiele gege bi Gomina ile ifowopamo naa. Šaaju akoko yi, o ti wa bi igbakeji gomina (Economic Policy), Central Bank of Nigeria lati 26 March 2007

Remove ads

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads