Senegal

From Wikipedia, the free encyclopedia

Senegal
Remove ads

Sẹ̀nẹ̀gàl (Faransé: le Sénégal) tabi Orile-ede Olominira ile Senegal je orile-ede ni Iwoorun Afrika. Senegal ni Okun Atlantiki ni iwoorun, Mauritania ni ariwa, Mali ni ilaorun, ati Guinea ati Guinea-Bissau ni guusu. Sinu die lo ku ko yipo Gambia ka patapata si ariwa, ilaorun ati guusu, ibi to se ku nikan ni eti okun Atlanti Gambia[4] Ifesi ile Senegal fe to 197,000 km², be si ni o ni onibugbe bi 18 milionu.

Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Sẹ̀nẹ̀gàl République du Sénégal, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...

Dakar ni oluilu re to wa lori Cap-Vert Peninsula ni eti Okun Atlantiki. Bi iye ida kan ninu meta awon ara Senegal ni won n gbe labe ila aini kakiriaye to je US$ 1.25 lojumo.[5]

Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads