Guinea-Bissau

From Wikipedia, the free encyclopedia

Guinea-Bissau
Remove ads

Guinea-Bissau tabi Orile-ede Olominira ile Guinea-Bissau (pípè /ˈɡɪni bɪˈsaʊ/; Pọrtugí: República da Guiné-Bissau, pípè [ʁɛˈpublikɐ dɐ ɡiˈnɛ biˈsaw]) budo si Iwoorun Afrika. O ni bode mo Senegal ni ariwa, ati Guinea ni guusu ati ilaorun, ati mo Okun Atlantiki ni iwoorun.

Quick facts Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Guinea-BissauRepublic of Guinea-Bissau República da Guiné-Bissau, Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ ...

Aala ile re to 37,000 square kilometres (14,000 sq mi) pelu awon olugbe ti idiye won to 1,600,000.

Guinea-Bissau je ara ileoba Gabu nigbakan, to je apa Ileobaluaye Mali; awon apa ileoba wa titi di orundun kejidinlogun, nigba ti awon miran si je apa Ileobaluaye Portugal. Nigba na lo wa di ibiamusin Portugal toruko re unje Guinea Portugi ni orundun 19. Leyin ilominira, to je fifilole ni o̩dún 1973 to si je didamo ni o̩dún 1974, oruko oluilu re, Bissau, je fifikun mo oruko orile-ede lati dena iaru po mo Orile-ede Olominira ile Guinea.

14% nikan ni awon olugbe ti won mo ede onibise, Portugi so. Awon 44% nso Kriol, ede to da lori Portugi, awon yioku nso awon ede abinibi Afrika. Awon esin kanka ibe ni esin Islam ati awon esin ibile Afrika.

O je omo egbe Isokan Afrika, Agbajo Okowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika, Agbajo Ipejo Onimale, Isokan Latini, Agbajo awon Orile-ede Ede Portugi, La Francophonie ati South Atlantic Peace and Cooperation Zone.

Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè tenikookan re je ikan larin awon tokerejulo lagbaye.

Remove ads

Itan


Ilominira


Iselu

Awon agbegbe ati apa ile Guinea-Bissau

Guinea-Bissau je pipin si awon agbegbe mé̩jo̩ ati apa ibi aladawa kan. Awon wonyi na tun wa je pinpin si apa metadinlogoji. Awon agbegbe ohun niyi:

  • Bafatá
  • Biombo
  • Bissau*
  • Bolama
  • Cacheu
  • Gabu
  • Oio
  • Quinara
  • Tombali
* autonomous sector
Thumb
Map of the regions of Guinea-Bissau

Jeografi


Awon ilu pataki

More information Cities in Guinea-Bissau, Rank ...
Remove ads

Ojuojo

Okowo

Aworan

Demografiki

Thumb
Líla odò ni kekere ṣiṣan
More information Religion in Guinea-Bissau, ...

Awon eya eniyan

Ede

Esin

Ilera

Eko

Asa


Orisun

  • Joshua B. Forrest, Lineages of State Fragility. Rural Civil Society in Guinea-Bissau (Ohio University Press/James Currey Ltd., 2003).
  • Richard Andrew Lobban, Jr. and Peter Karibe Mendy, Historical Dictionary of the Republic of Guinea-Bissau, third edition (Scarecrow Press, 1997) ISBN 0-8108-3226-7 (includes extensive bibliography)

Ijapo lode

Àdàkọ:Sisterlinks

Government
Awifun gbogbogbo
Iroyin

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads