Shelley Winters

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia

Shelley Winters
Remove ads

Shelley Winters (August 18, 1920 – January 14, 2006) jẹ óṣere lobinrin to gba Ebun Akademi bi Obinrin Osere Keji Didarajulo[1].

Quick Facts Ọjọ́ìbí, Aláìsí ...


Remove ads

Igbesi Aye Arabinrin naa

Shelley Winters jẹ óṣere lobinrin ilẹ amẹrica ti iṣẹ rẹ lọ fun ọdun mẹwa lọnọ meje ti ó si ti yọju ni óriṣiriṣi èrè agbelewo.Shelley ni a bini Shirley Schrift ni St.Louis, ilẹ Missouri. Óṣere lobinrin naa jẹ ọmọ Rose (Akọrin ni St. Louis Municipal Opera Theatre) ati Jonas Schrift (Oluran àṣọ awọn ọkunrin) ti wọn si jẹ ijọ ẹlẹsin jew[2].

Shelley fẹ ọkọ lẹmẹrin;

  • Captain Mack Paul Mayer ni ọjọ 29, óṣu December ni ọdun 1948. Awọn mejeji pinya ni ọdun 1948[3].
  • Vittorio Gassman ni ọjọ 28, óṣu April ni ọdun 1952. Awọn mejeji pinya ni óṣu june ni ọdun 1954[3].
  • Anthony Franciosa ni ọjọ kẹrin, óṣu May ni ọdun 1957. Awọn mejeji pinya ni ọjọ 18, óṣu November ni ọdun 1960[4].
  • Gerry DeFord ni ọjọ mẹtala, óṣu January ni ọdun 2006[5].

Shelly Winters ku ni ọmọ ọdun marun lèèlogọrin ni ọjọ kẹrin óṣú january ni ọdun 2006 lórin aisan ọkan ni Rehabilitation Center ti Beverly Hills[6].

Remove ads

Ẹkọ

Shelley lọsi ilè iwè jew ti ilẹ jamaica nibi ti arabinrin naa ti kọ orin hebrew. Óṣere lobinrin naa kọ èrè siṣè ni ilè iwè tuntun ni New York[7].

Ami Ẹyẹ Ati Idanilọla

Ami Ẹyẹ Akademi

More information Ọdun, Ipó ...

Ami Ẹyẹ Akademi Èrè Agbelewo ti Ilẹ British

More information Ọdun, Ipó ...

Ami Ẹyẹ ti Golden Globe

More information Ọdun, Ipó ...

Ami Ẹyẹ Primetime Emmy

More information Ọdun, Ipó ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads