Tìmọ́ọ̀tì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Tìmọ́ọ̀tì jẹ́ èso ewébẹ̀ àti ohun ọ̀gbìn tí a lè jẹ lásán, tàbí kí á slọ̀ọ́ pọ̀ mọ́ àwọn èròjà ìsebẹ̀ tó kù bí

Lílo Tìmọ́ọ̀tì

lílo tìmọ́ọ̀tì dá lórí irúfẹ́ Ọbẹ̀ tí a bá fẹ́ sè, àmọ́ tí a bá fi èròjà ìsebẹ̀ yí kún àwọn èlò ọbẹ̀ tókù, yóò mú kí Ọbaẹ̀ náà ó ní àádùn tó peregedé.[2][1] commonly known as a tomato plant. The species originated in western South America and Central America.[2][3]

[4][5][6]

Bí a ṣe ń jẹ tìmọ́ọ̀tì

Wọ́n ma ń lo tìmọ́ọ̀tì ní oríṣiríṣi ọ̀nà bí kí á fi á jẹ́ ní tútù tàbí kí a sèé lọ́bẹ̀, a lè fi se ónjẹ Salad, wọ́n sì tun ma ń fi ṣe ohun mímu ẹlẹ́rìn-dada.


Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads