Van Vicker

From Wikipedia, the free encyclopedia

Van Vicker
Remove ads

Joseph van Vicker (tí wọ́n bí ní 1 August 1977),[1] tí wọ́n tún mọ̀ sí Van Vicker, jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana, ó sì tún jẹ́ olùdarí eré àti aṣèfẹ́-ọmọnìyàn. Òun ni olùdarí ilé-iṣẹ́ Sky + Orange production, èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ tó ń ṣe fíìmù. Wọ́n yàn án fún àmì-ẹ̀yẹ méjì, àkọ́kọ́ fún "Òṣèrékùnrin tó dára jù nínú eré" àti "Òṣèrékùnrin tó ń di gbajúmọ̀ bọ̀" ní Africa Movie Academy Awards, ní ọdún 2008.[2][3]

Quick Facts Joseph van Vicker, Ọjọ́ìbí ...
Remove ads

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

Wọ́n bí Vicker ní ìlú Accra, ní Ghana. Ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ Ghana tó tan mọ́ ilẹ̀ Liberia[4], bàbá rẹ̀ sì jẹ́ ará Netherland.[5][6][7] Bàbá rẹ̀ kú nígbà tó wà ní ọmọdún mẹ́fà.[6]

Vicker lọ sí ilé-ìwé Mfantsipim,[8] pẹ̀lú òṣèrékùnrin ẹgbẹ́ rẹ̀, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Majid Michel. Ó gboyè ẹ̀kọ́ ní African University College of Communications, ní ọdún 2021.[9]

Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

More information Ọdún, Àmì-ẹ̀yẹ ...
Remove ads

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

More information Ọdún, Fíìmù ...

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads