Zenith bank
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Zenith Bank Plc jẹ́ ẹ̀ka ìfowópamọ ní ìlú Nìgíríà àti Anglophone apá iwọ̀ oòrùn Afíríkà . Ilé ìfowópamọ àpapọ̀ tí ìlú Nìgíríà tí fòǹtẹ̀ lu gẹ́gẹ́ bí ilé ìfowópamọ kéékèèké ,àjọ fún ètò ìfowópamọ ní ọjọ́ ọ́kànlélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 ní $16.1bn ni àkójọpọ̀ ìní wọn. Ilé Iṣẹ́ yìí wà lára Nigeria Stock Exchange àti London stock Exchange.[3][2] [4]


Remove ads
Remove ads
Àwọn ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads