From Wikipedia, the free encyclopedia
Àdàkọ:EngvarB Àdàkọ:Infobox dam
Hartbeespoort Dam (ti a tu mo si Harties) o je idido ti o wa ni Ariwa-Ilaorun ni South Africa. Owa ni ipetele to koju si guusu oke Magaliesberg ati Ariwa oke Witwatersberg, ni 35 kilomita si Ariwa-ilaorun Johannesburg ati 20 kilomita ilaorun Pretoria. Oruko idido naa tumo si 'Idido ni inu hartebeest" (iru Igala kan) ni Afrikaani. "Poort" yii ni Magaliesberg je ibi ti awón ode feran lati gegun de awón hartebeest.[1] Idi ti won se koko ko ididi yii ni ki I ma fun awón eso to won ti gbin ni omi, ati lati ma fun awón eranko ni omi.[2] [3]
y.[4]
Hartbeespoort dam | |
---|---|
Carries | Motor vehicle traffic |
Width | Single lane |
Toll | None |
Ni 1906 ni won bere isewadi boya won le ko idido ti o ma fun awón eranko ati agbe ni omi. Isé. 32 fun 1914 ni awon Ijoba gba pe ki won bere ise.[5] Ni 1909 ni won koko gbe iho ninu odo lati fi mo boya won le se idido si be.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.