Uche Chukwumerije (Oṣù kọkànlá Ọdún 1939 sí Ọjọ́ Ọkàndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún 2015) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú àríwá Abia, ìpínlẹ̀ Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Oṣù kẹrin Ọdún 2011 sí Oṣù kejìlá Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1]

Quick Facts Aṣojú àríwá Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà, Asíwájú ...
Uche Chukwumerije
Thumb
Aṣojú àríwá Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2003  Ọjọ́ ọ̀kàndínlógún Oṣù kẹrin Ọdún 2015
AsíwájúIke Nwachukwu
Arọ́pòTBD
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù kọkànlá ọdún 1939
ìpínlẹ̀ Abia, Nàìjíríà
Aláìsí2015
Abuja, Nigeria
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP
Close

Àwọn ìtọ́kasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.