Afo language
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Èdè Eloyi, tàbí Afu (Afo) tàbí Ajiri,[1] jẹ́ èdè tí àwọn ará ilé Plateau ń sọ. Èdè yìí jẹ́ èdè tí àwọn ará Ìlú Eloyi ni Agatu àti Otukpo ni Ìpínlẹ̀ Benue àti Nassarawa ní Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà ń sọ.
Remove ads
Ìsòrí
Armstrong ní Ọdún (1955, 1983)[2][3] Pín Ede Eloyi tàbí Afo sí ìsòrí, ó pín sí abẹ́ Èdè Idomo, ṣùgbọ́n ìdánimọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ èyí tí Armstrong padà ṣàfihàn iyèméjì.[4] àwọn ìgbìmò mìíràn pin sì abẹ́ Èdè Plateau. Àti pé Blench (2008) pin sábẹ́ ìsòrí mìíràn tí ó wà lábé Èdè ní Ìpínlẹ̀ Plateau [5].[6] Blench (2007) roò pé Eloyi jẹ́ onírúurú Èdè Plateau àmọ́ tí ó ní ipa Idomo èyí ó yẹ̀ kó jẹ́ ìdàkejì.[7]
Remove ads
Fonọ́lọ́jì
Kọ́ńsónántì
Fáwẹ́lì
Remove ads
Àwọn Àkọsílẹ̀
Àwọn Ìtọ́kasí
External links
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads