Alexander Van der Bellen (Pípè nì Jẹ́mánì: [alɛˈksandɐ fan deːɐ̯ ˈbɛlən]; ọjọ́ìbí 18 January 1944) ni Ààrẹ ilẹ̀ Austríà lọ́wọ́lọ́wọ́. Tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ ó ti ṣiṣẹ́ bíi ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀kọ́ ìmọ̀-ọ̀kọ̀wọ̀ ní Yunifásítì ìlú Vienna, bẹ́ẹ̀sìni lẹ́yìn ìgbà tó di olóṣèlú, ó di agbẹnusọ/olórí Ẹgbẹ́ Aláwọ̀-ẹwé ilẹ̀ Austríà.[2][3]
Quick facts President of Austria, Chancellor ...
Alexander Van der Bellen |
---|
 |
|
President of Austria |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga 26 January 2017 |
Chancellor | Christian Kern Sebastian Kurz Brigitte Bierlein Sebastian Kurz |
---|
Asíwájú | Heinz Fischer |
---|
Spokesman of the Green Party |
---|
In office 13 December 1997 – 3 October 2008 |
Asíwájú | Christoph Chorherr |
---|
Arọ́pò | Eva Glawischnig |
---|
Member of the National Council |
---|
In office 7 November 1994 – 5 July 2012 |
Nominated by | Peter Pilz |
---|
Affiliation | Green Party |
---|
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | Alexander Van der Bellen 18 Oṣù Kínní 1944 (1944-01-18) (ọmọ ọdún 81) Greater Vienna, Alpine and Danube Reichsgaue, Nazi Germany (present-day Vienna, Austria) |
---|
Aráàlú | |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent (2016–present) |
---|
Other political affiliations |
- Social Democratic Party (before 1992)
- Green Party (1992–2016)
|
---|
(Àwọn) olólùfẹ́ |
Brigitte Hüttner (m. 1962 ; div. 2015 )
Doris Schmidauer (m. 2015 )
|
---|
Àwọn ọmọ | 2 sons (with Brigitte) |
---|
Àwọn òbí | - Alma Sieboldt
- Alexander Van der Bellen
|
---|
Relatives | Van der Bellen family |
---|
Residence |
- Vienna (primary)[1]
- Kaunertal, Tyrol (secondary)
|
---|
Alma mater | University of Innsbruck (Dr. rer. oec.) |
---|
Profession | |
---|
Awards | List of honours and awards |
---|
Signature |  |
---|
Website | |
---|
Close