Ayu language

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Èdè Ayu jẹ́ èdè kan tí àwọn Olùsọ èdè náà kéré púpọ̀ ni àwọn agbègbè kan ni apá gúúsù ni Ìpínlẹ̀ Kaduna. Ó wá lábẹ́ ìsòrí èdè Plateau ṣùgbọ́n tí àwọn Olùsọ èdè na kéré díẹ̀. Bákan náà ìpín sì sórí rẹ sábẹ́ èdè Plateau kò ì tí dání lójú, ṣùgbọ́n ó lè wà lábẹ́ ìsòrí èdè Ninzic ni Blench 2008 sọ. Àwọn àgbà tí wọ́n ń sọ, mọ nípa èdè yìí, wọn kò fi lé ọmọ lọ́wọ́ kí wọ́n máa sọ èdè ayu.

Quick facts Sísọ ní, Ọjọ́ ìdásílẹ̀ ...


Ethnologue (22nd ed.) ṣe àtòjọ́ àwọn agbègbè àti ìlú tí a ti lè rí àwọn Olùsọ èdè yìí ni Agamati, Amantu, Ambel, Anka, Arau, Digel, Gwade, Ikwa, Kongon, ati Tayu ní Sanga ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.[1]

Remove ads

Àwọn Ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads