Eastern Acipa language
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Èdè Ìlà -oòrùn Acipa (tí wọ́n mọ̀ sí Zubazuba tàbí Səgəmuk) jẹ́ èdè Àwọn ará Kainji ni Ìpínlẹ̀ Kainji ni Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà. Yàtò díè wà ní àárín Achipa tí wọ́n ń sọ agbègbè ìwọ̀-oòrùn ṣùgbọ́n ará ìlú kan ní àwọn olú ìlú náà. Ní ọdún 1993, àkọsílẹ̀ wà pé àwọn èèyàn Ẹgbẹ̀rún Márùn-ún ni àwọn Olùsọ èdè yìí.[1] Àwọn tí wọ́n ń sọ èdè yìí ń pè èdè náà ni Tusəgəmuku.[2]
Ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ Western Acipa language.
Remove ads
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads