Eleftherios Venizelos

From Wikipedia, the free encyclopedia

Eleftherios Venizelos
Remove ads

Eleftherios Venizelos (tabi Elefthérios Kyriákou Venizélos, Griiki: Ελευθέριος Κυριάκου Βενιζέλος; 23 August 1864 – 18 March 1936) je Griiki eni pataki ati olori to se koko fun ibe ni ibere orundun 20th.[1][2][3] Won diboyan lopo igba gege bi Alakoso Agba ile Griisi lati 1910 de 1920 ati lati 1928 de 1932. Venizelos ko ipa pataki ninu oro abele ati ti okere ile Griisi to fi je pe won gba bi "oludasile ile Griisi odeoni",[4] be si ni won mo bi "Baba orile-ede".

Quick facts Elefthérios Venizélos (Gíríkì: Ελευθέριος Βενιζέλος), Prime Minister of Greece ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads