Halojín
From Wikipedia, the free encyclopedia
Remove ads
Àwọn halojín (tabi ẹ́límẹ́ntì halojín) ni egbe kan lori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti marun ti won fi kemika ba ara won tan, fluorínì (F), klorínì (Cl), brómìnì (Br), iodínì (I), àti astanínì (At). Elimenti 117 to je afowoda (ununseptium) na se e se ko je halojin. Ninu ifunloruko odeoni ti IUPAC, oruko egbe yi ni ẹgbẹ́ 17 (group 17) (tẹ́lẹ̀ bi: VII, VIIA, VIIB).

Noble gases
Halogens
Other nonmetals
Apart from hydrogen metallloids are not placed in the p-block.Egbe awon halojin nikan ni egbe ori tabili idasiko awon elimenti to ni awon elimenti ti won wa ni awon aye iwasi elo ti a mo meteeta ni igbonasi ati ifunpa onideede.
![]() |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Remove ads
Itokasi
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Remove ads