Astatínì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads

Astatínì tabi Astatine je apilese kemika alagbararadio pelu ami-idamo At ati nomba atomu 85. Ohun eyi towuwojulo keji ninu awon halojin. Botilejepe astatini nje mimuwaye nitori ijera alagbararadio ninu adanida, nitori short aabo emi kukuru re a le ri ni iye tintin. Astatini koko je mimuwaye latowo Dale R. Corson, Kenneth Ross MacKenzie, ati Emilio Segrè ni 1940. Odun meta koja ki o to dipe ipase astatini bakanna je wiwari ninu awon alumoni aladanida. Titi di aipe opolopo awon iwuwa aladanida ati kemika astatini je nipa sise afiwe mo awon apilese miran. Melo ninu awon isotopu astatini nje lilo bi olufonsita iwonwo alpha ninu awon imulo sayensi, be sini adanwo awon imulo oniwosan fun astatini 211 ti sele. Lowolowo astatini ni apilese aladanida to sowonjulo pelu idiye bi 30g ni o wa ninu igbele Aye.[2]

Quick Facts Pípè, Ìhànsójú ...
Remove ads

Itumosi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads