Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì

From Wikipedia, the free encyclopedia

Remove ads
Remove ads

Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì je ona eleto agbehan awon apilese egbo. Bo tile je pe iru tabili yi ti wa tele, eni ti gbogbo eniyan gba pe o da ni onimo khemistry Ararussia Dimitri Mandeleev ni odun 1869. Mandeleev fe tabili yi lati s'afihan ("igba") isele bi a se n da awon apilese mo. Atunse ti bo si iyasile tabili yi, be ni o si ti fe si bi a ba se n seawari awon apilese tuntun be sini a ti se iko apere elero (theoretical model) tuntun la ti se alaye iwuwa egbo.[1]

Thumb
Tábìlì àyè àwọn ẹ́límẹ̀ntì

Tabili igba ti je pataki nisinyi ninu imo eko Khemistry, nipa lati pin si owoowo, la si ona to mogbon wa ati lati safiwe awon orisirisi iru iwa egbo. Be na sini tabili yi n je lilo ninu eko Fisiki, Biology, imoero ati Ileise ero. Tabili ise (standard) isinyi ni 117 apilese ti a le fihan gege bi January 27, 2008 (nigbati apilese 118 ti je imudipo (synthesized) apilese 117 ko ti je be).


Remove ads

Ilanaoye ti a fi n sagbekale tabili igba

Tabili igba ise (Standard periodic table)

More information Group →, ↓ Period ...

Notes

  • Lanthanides are also known as "rare earth elements", a deprecated term. Regarding group membership of these elements, see here.
  • Alkali metals, alkaline earth metals, transition metals, actinides, lanthanides, and poor metals are all collectively known as "metals".
  • Halogens and noble gases are also non-metals.
More information Solids, Liquids ...


Alternative versions (Layout/view of the table)

  • Iru tabili ise bi ti oke yi je apere ipile.
  • Iru tabili anaro ti a le yi lo sile fun ojuewe to fun
  • Iru tabili gbangba fun wa ni ipile ati oruko awon apilese lekunrere
  • Iru tabili totobi fun ni awon toke pelu iposi atomu awon apilese
  • Iru tabili lekunrere
  • Iru tabili agbara imunawa
  • Iru Tábìlì ìgbà (iseto atanna)
  • Iru Tábìlì ìgbà (irin ati aije-irin)


Remove ads

Atosile

Iyasile tabili igba n safihan (igba) isele fun idamo awon egbo. A se akojo awon apilese bi nomba atomu won se n po si (eyun àkọ́wá ati inuikun atomu). Lori ila kanna ni awon apilese ti won ni idamo kanna wa ("akojopo")



Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads